เนื้อเพลง Fuji Vibe
Fuji Vibe - Asake
Lyrics by:Ololade Ahmed
Composed by:Ololade Ahmed
Produced by:Magicsticks/Asake/The Compozers
O ti pọ gan-an
Gan-an
Ẹ ma fi agilinti wọbọ o kẹ ma fi were we mi
Ẹni ba lọ lo le mọ a bọ le ṣalaye ni
Awọn ọmọ better ti pọ
Keep your money to ba n bọ
Lokeloke la ma lọ ẹ ri pe Balenciaga yẹn yatọ
Baby wa uhn uhn mi o raye k'eeyan fẹran kan jẹun
Oje lo jẹ uhn uhn ko n ṣe iwọ nikan ẹgbẹẹgbẹrun
Haba Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju
Ye is a mental
O lowo o lọ n loyun
Ah sukerike rike bumbum
Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan
Super extravagance lọmọ
Emi l'Asake medo t'ọn sọ
Baby you catch my feelings ahn ahn
I'm getting bigger
You dey shack my head like gbana
This your booty are you from Ghana
Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya ma ṣe jẹ k'ọn mọ
This your booty fit to jawaya o ga de sanmọ
Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza
Ọmọ olo mi ye ma gaza
No pressure wọn da mọ ọga Ade ẹni lọ lo bọ
Wọ America lọ fun tour
Akata wọn pọ lọpọ
Plenty plenty ọmọge
Wọn fẹ jẹ ki n sa nile
Ori mi lo yọ mi ọta i ba yọ mi
Ọmọ ọpẹ I dey find my way
Make bad belle no come stop my reign
Bẹbẹ n lọ like a moving train
Fun mi ni big big money no chicken change
Owo n bọ ọla n bọ alaafia ati igbadun n bọ
I no wan talk plenty talk my record can back it up
La-do-re-mi-fa-mi-so-la L'Eko
Oluwa ni ṣọla
Yarinya
Haba Vanessa ẹ bẹrẹ mu kẹ gboju
Ye is a mental
O lowo o lọ n loyun
Ah sukerike rike bumbum
Ẹ dẹ maa jo gan-an o di dandan
Super extravagance lọmọ
Emi l'Asake medo t'ọn sọ
Baby you catch my feelings ahn ahn
I'm getting bigger
You dey shack my head like gbana
This your booty are you from Ghana
Ọmọ olo mi ka ma nawọ ya ma ṣe jẹ k'ọn mọ
This your booty fit to jawaya o ga de sanmọ
Ibadi yẹn fẹ ki n ṣe wire into your aza
Ọmọ olo mi ye ma gaza
เกี่ยวกับเพลงนี้ :
Fuji Vibe ได้ถูกปล่อยออกมาเมื่อ 8 ส.ค. 2024. ดาวน์โหลด JOOX Application เพื่อฟังเพลง Fuji Vibe, รับชมมิวสิควิดีโอ, ฟังเพลงออนไลน์ และอ่านเนื้อเพลงออนไลน์ได้ทันที Fuji Vibe จาก Asake ฟังเพลง Fuji Vibe และสนุกสนานไปกับเสียงเพลงได้ทุกที่ทุกเวลา
Tags ที่เกี่ยวข้อง :
Fuji Vibe (โดย Asake), Fuji Vibe, Fuji Vibe มิวสิควีดีโอ, Fuji Vibe เนื้อเพลง, Asake เพลง