收聽Olamide的Hybrid歌詞歌曲

Hybrid

Olamide2025年6月18日

Hybrid 歌詞

Hybrid - Olamide

Lyrics by:Olamide Gbenga Adedeji

Composed by:Olamide Gbenga Adedeji

Produced by:Magicsticks

Fly to Paris for fitting

Go Cali for meeting

Ibiza mo turn up

Maimi mo de'bẹ

Nokia Turaya

Laye mi o le tire

Gba local gba wire

Eeyan Suko I dey fire

Mo local bi Fuji

Like MJ mo boggie

Pa a danu fun un lọrun

I been killing this game Ọlọrun

Mo gaza mo gaza

Ẹjọ riro I no get answer

Send money to aza

I dey para gidi gan-an is a maza

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye?

Owo mi da?

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Don't be a ******* bastard

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye?

Awọn temi wọn n gba lavida

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye?

I no fit joke with my last card

Banusọ ma beniyan sọ

Ko ku si pressure

O ni railway o ku ni busstop

Mo gbe fun

Gbasgbos

Mo gbe fun

Gbosgbas

Nẹnẹnẹ

Ṣọki ṣọmbọlọ

Ṣọmọ lọ

One on one maa dẹmọ

Ọpọlọ plus ọpọlọ is equal to ọpọlọ

Baby no wan quanta

Wan die on the matter

Because I no be pata

Hustle blow money like a Santa

Party like Poco

Gbe body like Jago

Ọpọlọ Igbo like Zanku

When the gbẹdu drop baby wọn a ku

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye?

Owo mi da?

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Don't be a ******* bastard

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye?

Awọn temi wọn n gba lavida

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye

Ṣo n ye ṣo n ye ṣo n ye?

 

I no fit joke with my last card